Mura SILE DE JESU
Mura sile dee, on pada bó ooo
Jesu nbo lati ka yanfe lóó
O nbo ninu ogo ninu olanle re
Jesu nbo lekeji e mura sile
1. Jesu nbo wa funjo ti ko ni abawon
Ijo ta feje ra to mo laulau
Ijo to ngbadura to n wasu ihinrere
Jesu nbo lekeji nibo lo fe wa
2. Ara MI loni nje emura tan nje
En gbadura fun bibo Jesu, ni ojo
Idajo tayanfe yo fo lo si ile wa
Loke nibo lofe wa.
Mura sile dee, on pada bó ooo
Jesu nbo lati ka yanfe lóó
O nbo ninu ogo ninu olanle re
Jesu nbo lekeji e mura sile
1. Jesu nbo wa funjo ti ko ni abawon
Ijo ta feje ra to mo laulau
Ijo to ngbadura to n wasu ihinrere
Jesu nbo lekeji nibo lo fe wa
2. Ara MI loni nje emura tan nje
En gbadura fun bibo Jesu, ni ojo
Idajo tayanfe yo fo lo si ile wa
Loke nibo lofe wa.
Comments
Post a Comment